Wird geladen....
Drücken und Halten zum Ziehen |
|||
Hier klicken, um zu schließen |
Frage 1 Bericht
ÈDÈ
Nínú ßadé a máa lô söjà ôrôôrún, ibá-ìÿêlê tó je yô ni
Antwortdetails
Nítorí pé ßadé ÿí n lô sõjà ôrôôrún.
Frage 2 Bericht
ÌßÊßE
Àsìkò wo ni a máa þ ÿe eré ìdárayá?
Frage 3 Bericht
ÈDÈ
Àbùdá tí ó þ fi iye sílébù hàn ni
Frage 4 Bericht
ÌßÊßE
Çgbë-n-bígbo, àbí àjùmõ-gbélé-põ?
Ta ló lè pèdè yìí síni?
Antwortdetails
Çni tó juni lô le è ÿô bëê láti fí hàn pé òún ju olúwarê lô.
Frage 5 Bericht
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Àkójôpõ Ewi Alohùn Yorùbá ni ìbéèrè dá lé.
Nínú Èfê, kí ni àÿírí ìyàwó õgá Súlè tí õkôrin tú?
Frage 6 Bericht
ÈDÈ
Èwo nínú ìwõnyi ló ní möfíìmù ìÿêdá kan?
Antwortdetails
Kò sí ìdáhùn nínú õrõ mërêêrin nítorí pé gbogbo wôn ló ní ju
möfíìmù ìÿêda kan.
Frage 7 Bericht
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Àÿírí Amòòkùnjalè Tú ni ìbéèrè dá lé.
Õrë Orínmóògùnjë ti ó þ bá a ra kòkó ni
Antwortdetails
Õrë tímötímö ni orímóògùnjë àtí Ajíÿefínní.
Frage 8 Bericht
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Ìyán Ogún Ôdún ni ìbéèrè dá lé.
Ta ni ìyàwó Arówóná?
Frage 9 Bericht
ÈDÈ
Àkôtö gan ní
Frage 10 Bericht
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Ilé-ayé ò jë nýkan,
Àlá lásán ni,
Ôkàn tó þ sùn ti dòkú,
Nýkan ò rí bí a ti rò ó
Ilé-ayé gbçgë. 5
Sàréè ì ÿopin êdá.
Eérú fún eérú,
Eruku fún eruku,
Lôba-òkè sô fénìyàn,
Tó j’Ôlörun nípè. 10
Àmö hùwà bí çni pé,
Ojoojúmö lêdá þ súnmölé.
Máà gbëkêké ôlá
Máà nígbçkêlé nínú ôrõ.
Alágbára ayé, ç rôra ÿe. 15
Bí ó ti wù ká ki lökàn tó,
Kìkì ní í lù,
Báa bá gbölù ikú,
Àtorin arò ti þ kôjá lóde.
Ojú ogun layé. 20
Má bojú wêyìn,
Jà bí akin lójú ìjà.
Rántí ayé àkôni tó kôjá,
Wo àwòköÿe wôn fún ôjö õla tìrç.
Gbé ìgbé-ayé alààyè, 25
Jë kí òkú sunkún ara wôn.
Àwé, má ronú mö,
Jë ká máa ÿiÿé lô.
Máa jagun lô,
Má wêyìn, 30
Má ÿiyè méjì,
Bó pë, bó yá,
Ayõ þ bõ.
... i ní ìlà 17 töka sí
Frage 11 Bericht
ÌßÊßE
Níbo ni ètò ìsèlú láàrin àwôn Yorùba ti bêrê?
Antwortdetails
Bàbá àti ìyá ni olórí ilé àti alákòóÿo ilé.
Frage 12 Bericht
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Babárìndé nífêë Fôláÿadé púpõ. Fôláÿadé náà sì rèé, òrékelëwà ômôge, çlëyinjú-çgë, çlërin-ín êyç! Òun náà sì dá ìfë yìí padà pêlú ayõ àti ìdùnnú. ßùgbön bàbá Fôláÿadé ni igi wörökö tí þ da iná rú nídìí õrõ yìí: ó kórìíra Babárìndé nítorí pé ó kà á sí òtòÿì ènìyàn.Bëê ômôlójú rê sì ni Fôláÿadé í ÿe. Baba gbàgbö pé bí ômô òun bá fë Babárìndé, inú ìyà ni tôkôtaya wôn yóò wà.
Kì í kúkú í ÿe pé Babárìndé jë tálákà bëê náà: ó þ ÿiÿë gëgë bí òÿìÿë kékeré nílé-iÿë þlá kan, bëê ni kò sì tôrô jç, ÿùgbön ó kàn jë pé kò lówó tó Ayõkúnlé Atáyéwá, oníÿòwò kan tí baba Fôláÿadé fë kí ômô rê fë. Ìyá Fôláÿadé náà sì rèé, ibi tí ôkô rê bá tê sí ni òun náà þ tê sí. ßé ojúbõrõ kö ni a sì fi þ gbômô löwö èkùrö: àwôn òbí Fôláÿadé fi toògùn-toògùn fa ômô wôn fún Ayõkúnlé Atáyéwá ÿaya. Babárìndé banújë nídìí õrõ yìí, êdùn-ôkàn sì ni Fôláÿadé gbé wôlé ôkô.
Ôjö þ gorí ôjö, ôdún þ gorí ôdún, bëê ni ìgbà sì þ rékôjá lo. Fôláÿadé bí akô, ó bi abo nílé ôkô, ÿúgbön nýkan ò lô déédé fún ôkô rê mö lënu òwò rè. Àwôn oníbodè ti gbësê lé ôjà rê tó jë çgbêlëgbê náírà. Ó yáwó nílé-ìfowópamö, ÿùgbön kò rí i san padà. Àwôn báýkì bá gba ilé, ôkõ àti àwôn dúkìá rê mìíràn. Àtijç-àtimu wá di ìÿòro fún òun àti ìyàwó rê àti àwon ômô wôn pêlú.
Níhà kejì, Babárìndé náà ti gbéyàwó, ó sì tí bímô. Lënu iÿë rê wàyìí, ó ti di õgá, orí sì ti sún un sölá. Àwôn òbí Fôláÿadé wá þ wò sùnùn, wön rí i bí ìgbé-ayé Ayõkúnlé Atáyéwá ÿe þ lô, wön sì tún wo ti Fôláÿadé ômô wôn, bákan náà ni wön sì þ gbókèèrè wo ti Babárìndé bó ÿe þ dùn sí i fún un. Wön wá fika àbámò bônu: iwájú ò ÿeé lô, èyìn ò sì ÿeé padà sí fún wôn. Babárìndé, eni tí wôn rò pé kò lè pàgö ló wá dçni tí þ kölé aláruru. Ó wá hàn kedere sí wôn pé çni tí yóò dôlölà löla, orí ló mõ ön.
Fôláÿadé gbé êdùn-ôkàn wôlékô nítorí pé
Antwortdetails
Nítorí pe àwôn bàbá rê kò jë kó fë çni tó wù ú.
Frage 13 Bericht
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Àÿàyàn Àlö Onítàn ni ìbéèrè dá lé.
Nínú ìtán Ômô Onífèrè àti Àwôn Òbí rè, ômô mélòó ni bàbá olóko þlá bí?
Antwortdetails
Olóko þlá kò bí ju ômô méta.
Frage 14 Bericht
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Ìgbá Lonígbàá Kà ni ìbéèrè dá lé.
Nínú Gbágùúdá, oúnjç wo ni ‘baálê’ ohun tí à þ fêgë ÿe?
Antwortdetails
Gààrí ló wöpõ jù nínú ohun tí a þ fi gbágúdá ÿe.
Frage 15 Bericht
ÌßÊßE
Kí ni a fi þ gbé pósí òkú sínú ìbojì nílê Yorùbá?
Antwortdetails
The question is asking what Yoruba people put in a coffin during burial to represent a deceased person's possessions or attributes. The answer is Aÿô, which is a type of cloth that is traditionally used to wrap items in Yoruba culture. It is believed that the cloth carries the essence and memories of the person being buried, and so it is placed in the coffin to represent their possessions or attributes.
Frage 16 Bericht
ÈDÈ
Fáwëlì àìránmúpè àyanupè ààrin pçrçsç ni
Frage 17 Bericht
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Babárìndé nífêë Fôláÿadé púpõ. Fôláÿadé náà sì rèé, òrékelëwà ômôge, çlëyinjú-çgë, çlërin-ín êyç! Òun náà sì dá ìfë yìí padà pêlú ayõ àti ìdùnnú. ßùgbön bàbá Fôláÿadé ni igi wörökö tí þ da iná rú nídìí õrõ yìí: ó kórìíra Babárìndé nítorí pé ó kà á sí òtòÿì ènìyàn.Bëê ômôlójú rê sì ni Fôláÿadé í ÿe. Baba gbàgbö pé bí ômô òun bá fë Babárìndé, inú ìyà ni tôkôtaya wôn yóò wà.
Kì í kúkú í ÿe pé Babárìndé jë tálákà bëê náà: ó þ ÿiÿë gëgë bí òÿìÿë kékeré nílé-iÿë þlá kan, bëê ni kò sì tôrô jç, ÿùgbön ó kàn jë pé kò lówó tó Ayõkúnlé Atáyéwá, oníÿòwò kan tí baba Fôláÿadé fë kí ômô rê fë. Ìyá Fôláÿadé náà sì rèé, ibi tí ôkô rê bá tê sí ni òun náà þ tê sí. ßé ojúbõrõ kö ni a sì fi þ gbômô löwö èkùrö: àwôn òbí Fôláÿadé fi toògùn-toògùn fa ômô wôn fún Ayõkúnlé Atáyéwá ÿaya. Babárìndé banújë nídìí õrõ yìí, êdùn-ôkàn sì ni Fôláÿadé gbé wôlé ôkô.
Ôjö þ gorí ôjö, ôdún þ gorí ôdún, bëê ni ìgbà sì þ rékôjá lo. Fôláÿadé bí akô, ó bi abo nílé ôkô, ÿúgbön nýkan ò lô déédé fún ôkô rê mö lënu òwò rè. Àwôn oníbodè ti gbësê lé ôjà rê tó jë çgbêlëgbê náírà. Ó yáwó nílé-ìfowópamö, ÿùgbön kò rí i san padà. Àwôn báýkì bá gba ilé, ôkõ àti àwôn dúkìá rê mìíràn. Àtijç-àtimu wá di ìÿòro fún òun àti ìyàwó rê àti àwon ômô wôn pêlú.
Níhà kejì, Babárìndé náà ti gbéyàwó, ó sì tí bímô. Lënu iÿë rê wàyìí, ó ti di õgá, orí sì ti sún un sölá. Àwôn òbí Fôláÿadé wá þ wò sùnùn, wön rí i bí ìgbé-ayé Ayõkúnlé Atáyéwá ÿe þ lô, wön sì tún wo ti Fôláÿadé ômô wôn, bákan náà ni wön sì þ gbókèèrè wo ti Babárìndé bó ÿe þ dùn sí i fún un. Wön wá fika àbámò bônu: iwájú ò ÿeé lô, èyìn ò sì ÿeé padà sí fún wôn. Babárìndé, eni tí wôn rò pé kò lè pàgö ló wá dçni tí þ kölé aláruru. Ó wá hàn kedere sí wôn pé çni tí yóò dôlölà löla, orí ló mõ ön.
Ohun tó mú àyípadà burúkú bá Atáyéwá ni pé
Frage 18 Bericht
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Ilé-ayé ò jë nýkan,
Àlá lásán ni,
Ôkàn tó þ sùn ti dòkú,
Nýkan ò rí bí a ti rò ó
Ilé-ayé gbçgë. 5
Sàréè ì ÿopin êdá.
Eérú fún eérú,
Eruku fún eruku,
Lôba-òkè sô fénìyàn,
Tó j’Ôlörun nípè. 10
Àmö hùwà bí çni pé,
Ojoojúmö lêdá þ súnmölé.
Máà gbëkêké ôlá
Máà nígbçkêlé nínú ôrõ.
Alágbára ayé, ç rôra ÿe. 15
Bí ó ti wù ká ki lökàn tó,
Kìkì ní í lù,
Báa bá gbölù ikú,
Àtorin arò ti þ kôjá lóde.
Ojú ogun layé. 20
Má bojú wêyìn,
Jà bí akin lójú ìjà.
Rántí ayé àkôni tó kôjá,
Wo àwòköÿe wôn fún ôjö õla tìrç.
Gbé ìgbé-ayé alààyè, 25
Jë kí òkú sunkún ara wôn.
Àwé, má ronú mö,
Jë ká máa ÿiÿé lô.
Máa jagun lô,
Má wêyìn, 30
Má ÿiyè méjì,
Bó pë, bó yá,
Ayõ þ bõ.
Níbo ni akéwì fi wé ojú ìjà?
Antwortdetails
Yorùbá gbà pé àwa ènìyàn wá ja ogun nílé ayé ni
Frage 19 Bericht
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Àÿàyàn Àlö Onítàn ni ìbéèrè dá lé.
Nínú ìtàn Ìdí tí Çyç Àkókó ÿe þ fçnu sô igi, ta ni àwôn ôkùnrin þ dù láti fë?
Frage 20 Bericht
ÌßÊßE
Õkan nínú ohun tí a fi þ ÿe ìtöjú aláìsàn ni
Antwortdetails
Òògùn ti a fi þ wo aláisàn nílê Yorùbá ni àgbo.
Frage 21 Bericht
ÈDÈ
Àpapõ jô àti mi yóò jë
Frage 22 Bericht
ÈDÈ
ße ìtumõ ‘The committee will took into the crisis’.
Antwortdetails
The sentence "The committee will took into the crisis" is incorrect. The correct form of the sentence should be "The committee will look into the crisis." In this sentence, the correct verb to use is "look" and not "took". Therefore, the correct option is: "Ìgbìmõ á lè dá sí aáwõ náà" which means "The committee can look into the crisis."
Frage 23 Bericht
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Babárìndé nífêë Fôláÿadé púpõ. Fôláÿadé náà sì rèé, òrékelëwà ômôge, çlëyinjú-çgë, çlërin-ín êyç! Òun náà sì dá ìfë yìí padà pêlú ayõ àti ìdùnnú. ßùgbön bàbá Fôláÿadé ni igi wörökö tí þ da iná rú nídìí õrõ yìí: ó kórìíra Babárìndé nítorí pé ó kà á sí òtòÿì ènìyàn.Bëê ômôlójú rê sì ni Fôláÿadé í ÿe. Baba gbàgbö pé bí ômô òun bá fë Babárìndé, inú ìyà ni tôkôtaya wôn yóò wà.
Kì í kúkú í ÿe pé Babárìndé jë tálákà bëê náà: ó þ ÿiÿë gëgë bí òÿìÿë kékeré nílé-iÿë þlá kan, bëê ni kò sì tôrô jç, ÿùgbön ó kàn jë pé kò lówó tó Ayõkúnlé Atáyéwá, oníÿòwò kan tí baba Fôláÿadé fë kí ômô rê fë. Ìyá Fôláÿadé náà sì rèé, ibi tí ôkô rê bá tê sí ni òun náà þ tê sí. ßé ojúbõrõ kö ni a sì fi þ gbômô löwö èkùrö: àwôn òbí Fôláÿadé fi toògùn-toògùn fa ômô wôn fún Ayõkúnlé Atáyéwá ÿaya. Babárìndé banújë nídìí õrõ yìí, êdùn-ôkàn sì ni Fôláÿadé gbé wôlé ôkô.
Ôjö þ gorí ôjö, ôdún þ gorí ôdún, bëê ni ìgbà sì þ rékôjá lo. Fôláÿadé bí akô, ó bi abo nílé ôkô, ÿúgbön nýkan ò lô déédé fún ôkô rê mö lënu òwò rè. Àwôn oníbodè ti gbësê lé ôjà rê tó jë çgbêlëgbê náírà. Ó yáwó nílé-ìfowópamö, ÿùgbön kò rí i san padà. Àwôn báýkì bá gba ilé, ôkõ àti àwôn dúkìá rê mìíràn. Àtijç-àtimu wá di ìÿòro fún òun àti ìyàwó rê àti àwon ômô wôn pêlú.
Níhà kejì, Babárìndé náà ti gbéyàwó, ó sì tí bímô. Lënu iÿë rê wàyìí, ó ti di õgá, orí sì ti sún un sölá. Àwôn òbí Fôláÿadé wá þ wò sùnùn, wön rí i bí ìgbé-ayé Ayõkúnlé Atáyéwá ÿe þ lô, wön sì tún wo ti Fôláÿadé ômô wôn, bákan náà ni wön sì þ gbókèèrè wo ti Babárìndé bó ÿe þ dùn sí i fún un. Wön wá fika àbámò bônu: iwájú ò ÿeé lô, èyìn ò sì ÿeé padà sí fún wôn. Babárìndé, eni tí wôn rò pé kò lè pàgö ló wá dçni tí þ kölé aláruru. Ó wá hàn kedere sí wôn pé çni tí yóò dôlölà löla, orí ló mõ ön.
Êkö pàtàkì tí àyôkà yìí köni ni pé
Frage 24 Bericht
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Ìyán Ogún Ôdún ni ìbéèrè dá lé.
Çni tó kó gbogbo ômô-ogun jô tó sì ÿètò ìjagun ni
Frage 25 Bericht
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Ìyán Ogún Ôdún ni ìbéèrè dá lé.
Ta ni ó dábàá Ifábùnmi fún oyè Balógun?
Antwortdetails
Òun ni õrë rê.
Frage 27 Bericht
ÌßÊßE
Èwo ni ó fi ìgbàgbö Yorùbá nípa ayé lëyìn ikú hàn nínú ìwònyí?
Antwortdetails
Yorùbá gbàgbö pé àwôn êdá tí wön ti kú tí wön tõrun wá sí ayé ni egúngún.
Frage 28 Bericht
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Ilé-ayé ò jë nýkan,
Àlá lásán ni,
Ôkàn tó þ sùn ti dòkú,
Nýkan ò rí bí a ti rò ó
Ilé-ayé gbçgë. 5
Sàréè ì ÿopin êdá.
Eérú fún eérú,
Eruku fún eruku,
Lôba-òkè sô fénìyàn,
Tó j’Ôlörun nípè. 10
Àmö hùwà bí çni pé,
Ojoojúmö lêdá þ súnmölé.
Máà gbëkêké ôlá
Máà nígbçkêlé nínú ôrõ.
Alágbára ayé, ç rôra ÿe. 15
Bí ó ti wù ká ki lökàn tó,
Kìkì ní í lù,
Báa bá gbölù ikú,
Àtorin arò ti þ kôjá lóde.
Ojú ogun layé. 20
Má bojú wêyìn,
Jà bí akin lójú ìjà.
Rántí ayé àkôni tó kôjá,
Wo àwòköÿe wôn fún ôjö õla tìrç.
Gbé ìgbé-ayé alààyè, 25
Jë kí òkú sunkún ara wôn.
Àwé, má ronú mö,
Jë ká máa ÿiÿé lô.
Máa jagun lô,
Má wêyìn, 30
Má ÿiyè méjì,
Bó pë, bó yá,
Ayõ þ bõ.
Níbo ni òpin êdá?
Antwortdetails
Lödõ Ôlörun tó dá êdá ni yóò ti lô jë àbõ löjö tí ikú bá dé.
Frage 29 Bericht
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Àÿírí Amòòkùnjalè Tú ni ìbéèrè dá lé.
Çni ti `awôn ènìyàn fura sí jù nípa owó tó pòórá ni
Antwortdetails
Òun ló dúró ti Àkàngbé nígbà tí ara rê kò yá, nínú ìyêwù rê sì ni owó ti sônù.
Frage 30 Bericht
ÈDÈ
Nínú Mò þ gààrí rê, gààrí
Antwortdetails
The question is asking about the main ingredient in "Mo papo garri" which is a popular West African snack made from cassava. The correct answer would be "õrõ-ìÿe", which means "ground cassava". This is because garri is made by peeling, washing, and grinding cassava roots into a paste, which is then fermented and sieved to produce granules that are roasted into the final product.
Frage 31 Bericht
ÌßÊßE
Ìwà ômôlúàbí ni kí a
Antwortdetails
Idahun ti o tona ni C
Explanation: ti a ba ran omo ni ise eru afi ti omo je iyen Yoruba fi n pe eyan ni omoluabi
Fi eje sinu tuto funfun jade tumo si wipe ki eniyan ma ro ero ki ero ko si ma so idakeji re jade.
Frage 32 Bericht
ÈDÈ
Àfòmö ìbêrê ni a fi ÿêdá
Frage 33 Bericht
Antwortdetails
The question is asking which group of people among the options given do not have any say or contribution to decision-making in the meeting of the Ìyanÿélódi. - Ejò àtewúrë refers to the youngest age grade set in Yoruba land who are yet to be initiated into adulthood, they are not allowed to participate in decision-making meetings. - Çran àtaláýgbá refers to the elders council in the community, who are highly respected and have a say in decision making. - Àwọn àgbà õjẹ́ refers to the women council, who also have a say in decision-making meetings. - Àwọn õtõkùlú refers to the age grade set in Yoruba land who have already been initiated into adulthood and are eligible to participate in decision-making meetings. Therefore, the group of people who do not have any say or contribution to decision-making in the meeting of the Ìyanÿélódi are the ejò àtewúrë (youngest age grade set).
Frage 34 Bericht
ÌßÊßE
Èwo ni ìgbésê àkökö nínú àÿà ìgbéyàwó?
Antwortdetails
Ôkùnrin tó bá þ wá ìyàwó gbödõ kökö máa fojú wá ìyàwó tó wù u láti fë.
Frage 35 Bericht
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Àkójôpõ Ewi Alohùn Yorùbá ni ìbéèrè dá lé.
Nínú Ìjálá, kí ni õkôrin sô pé ó máa þ gbêyìn àlè?
Antwortdetails
Nítorí pé kì í sí ìfë àtôkànwá láàrin àlè méji.
Frage 36 Bericht
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Àÿírí Amòòkùnjalè Tú ni ìbéèrè dá lé.
Kí ni ó fa ìjà lábúlé Alágbèdç?
Antwortdetails
Èrò ôkõ kan ló bá awakõ jà nítorí múrí méjì.
Frage 38 Bericht
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Ìgbá Lonígbàá Kà ni ìbéèrè dá lé.
Nínú Owó, ohun ti akéwì dàníyàn kí ó pa òun ti ni
Antwortdetails
Nítorí pé òÿì kì í ÿe ohun tó dára nínú ayé ènìyàn.
Frage 39 Bericht
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Àÿàyàn Àlö Onítàn ni ìbéèrè dá lé.
‘Nínú ìtàn Ôdç kan àti Õrê rè, eni tí ó fí ibi ÿú olóore ni
Frage 40 Bericht
ÈDÈ
Bí F1 bá jë e, F2 yóò jë
Antwortdetails
“u” nikan ló lè bá “e” köwõö rìn. b. a. eku.
Frage 41 Bericht
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Ilé-ayé ò jë nýkan,
Àlá lásán ni,
Ôkàn tó þ sùn ti dòkú,
Nýkan ò rí bí a ti rò ó
Ilé-ayé gbçgë. 5
Sàréè ì ÿopin êdá.
Eérú fún eérú,
Eruku fún eruku,
Lôba-òkè sô fénìyàn,
Tó j’Ôlörun nípè. 10
Àmö hùwà bí çni pé,
Ojoojúmö lêdá þ súnmölé.
Máà gbëkêké ôlá
Máà nígbçkêlé nínú ôrõ.
Alágbára ayé, ç rôra ÿe. 15
Bí ó ti wù ká ki lökàn tó,
Kìkì ní í lù,
Báa bá gbölù ikú,
Àtorin arò ti þ kôjá lóde.
Ojú ogun layé. 20
Má bojú wêyìn,
Jà bí akin lójú ìjà.
Rántí ayé àkôni tó kôjá,
Wo àwòköÿe wôn fún ôjö õla tìrç.
Gbé ìgbé-ayé alààyè, 25
Jë kí òkú sunkún ara wôn.
Àwé, má ronú mö,
Jë ká máa ÿiÿé lô.
Máa jagun lô,
Má wêyìn, 30
Má ÿiyè méjì,
Bó pë, bó yá,
Ayõ þ bõ.
Àwé túmõ sí
Frage 42 Bericht
ÌßÊßE
Dídá àásó çwà sí wöpõ láàrin àwôn
Frage 43 Bericht
ÈDÈ
Àgbê ni mo ri jë gbólóhùn
Frage 44 Bericht
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Àkójôpõ Ewi Alohùn Yorùbá ni ìbéèrè dá lé.
Nínú Dadakúàdà, oríkì Aájì Báyò ni
Frage 45 Bericht
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Babárìndé nífêë Fôláÿadé púpõ. Fôláÿadé náà sì rèé, òrékelëwà ômôge, çlëyinjú-çgë, çlërin-ín êyç! Òun náà sì dá ìfë yìí padà pêlú ayõ àti ìdùnnú. ßùgbön bàbá Fôláÿadé ni igi wörökö tí þ da iná rú nídìí õrõ yìí: ó kórìíra Babárìndé nítorí pé ó kà á sí òtòÿì ènìyàn.Bëê ômôlójú rê sì ni Fôláÿadé í ÿe. Baba gbàgbö pé bí ômô òun bá fë Babárìndé, inú ìyà ni tôkôtaya wôn yóò wà.
Kì í kúkú í ÿe pé Babárìndé jë tálákà bëê náà: ó þ ÿiÿë gëgë bí òÿìÿë kékeré nílé-iÿë þlá kan, bëê ni kò sì tôrô jç, ÿùgbön ó kàn jë pé kò lówó tó Ayõkúnlé Atáyéwá, oníÿòwò kan tí baba Fôláÿadé fë kí ômô rê fë. Ìyá Fôláÿadé náà sì rèé, ibi tí ôkô rê bá tê sí ni òun náà þ tê sí. ßé ojúbõrõ kö ni a sì fi þ gbômô löwö èkùrö: àwôn òbí Fôláÿadé fi toògùn-toògùn fa ômô wôn fún Ayõkúnlé Atáyéwá ÿaya. Babárìndé banújë nídìí õrõ yìí, êdùn-ôkàn sì ni Fôláÿadé gbé wôlé ôkô.
Ôjö þ gorí ôjö, ôdún þ gorí ôdún, bëê ni ìgbà sì þ rékôjá lo. Fôláÿadé bí akô, ó bi abo nílé ôkô, ÿúgbön nýkan ò lô déédé fún ôkô rê mö lënu òwò rè. Àwôn oníbodè ti gbësê lé ôjà rê tó jë çgbêlëgbê náírà. Ó yáwó nílé-ìfowópamö, ÿùgbön kò rí i san padà. Àwôn báýkì bá gba ilé, ôkõ àti àwôn dúkìá rê mìíràn. Àtijç-àtimu wá di ìÿòro fún òun àti ìyàwó rê àti àwon ômô wôn pêlú.
Níhà kejì, Babárìndé náà ti gbéyàwó, ó sì tí bímô. Lënu iÿë rê wàyìí, ó ti di õgá, orí sì ti sún un sölá. Àwôn òbí Fôláÿadé wá þ wò sùnùn, wön rí i bí ìgbé-ayé Ayõkúnlé Atáyéwá ÿe þ lô, wön sì tún wo ti Fôláÿadé ômô wôn, bákan náà ni wön sì þ gbókèèrè wo ti Babárìndé bó ÿe þ dùn sí i fún un. Wön wá fika àbámò bônu: iwájú ò ÿeé lô, èyìn ò sì ÿeé padà sí fún wôn. Babárìndé, eni tí wôn rò pé kò lè pàgö ló wá dçni tí þ kölé aláruru. Ó wá hàn kedere sí wôn pé çni tí yóò dôlölà löla, orí ló mõ ön.
Àwôn òbí Fôláÿadé kábàámõ ìwà wôn nítorí pé
Antwortdetails
Babárìndé tí wön ròpin di ènìyàn pàtàkì ÿùgbön Atáyéwá di òtòÿì.
Frage 46 Bericht
ÈDÈ
Àkôtö tí ó tõnà ni
Frage 47 Bericht
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Ilé-ayé ò jë nýkan,
Àlá lásán ni,
Ôkàn tó þ sùn ti dòkú,
Nýkan ò rí bí a ti rò ó
Ilé-ayé gbçgë. 5
Sàréè ì ÿopin êdá.
Eérú fún eérú,
Eruku fún eruku,
Lôba-òkè sô fénìyàn,
Tó j’Ôlörun nípè. 10
Àmö hùwà bí çni pé,
Ojoojúmö lêdá þ súnmölé.
Máà gbëkêké ôlá
Máà nígbçkêlé nínú ôrõ.
Alágbára ayé, ç rôra ÿe. 15
Bí ó ti wù ká ki lökàn tó,
Kìkì ní í lù,
Báa bá gbölù ikú,
Àtorin arò ti þ kôjá lóde.
Ojú ogun layé. 20
Má bojú wêyìn,
Jà bí akin lójú ìjà.
Rántí ayé àkôni tó kôjá,
Wo àwòköÿe wôn fún ôjö õla tìrç.
Gbé ìgbé-ayé alààyè, 25
Jë kí òkú sunkún ara wôn.
Àwé, má ronú mö,
Jë ká máa ÿiÿé lô.
Máa jagun lô,
Má wêyìn, 30
Má ÿiyè méjì,
Bó pë, bó yá,
Ayõ þ bõ.
Kí ni akéwì sô pé yóò ÿe êdá tó gbö nípa ikú?
Frage 48 Bericht
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Babárìndé nífêë Fôláÿadé púpõ. Fôláÿadé náà sì rèé, òrékelëwà ômôge, çlëyinjú-çgë, çlërin-ín êyç! Òun náà sì dá ìfë yìí padà pêlú ayõ àti ìdùnnú. ßùgbön bàbá Fôláÿadé ni igi wörökö tí þ da iná rú nídìí õrõ yìí: ó kórìíra Babárìndé nítorí pé ó kà á sí òtòÿì ènìyàn.Bëê ômôlójú rê sì ni Fôláÿadé í ÿe. Baba gbàgbö pé bí ômô òun bá fë Babárìndé, inú ìyà ni tôkôtaya wôn yóò wà.
Kì í kúkú í ÿe pé Babárìndé jë tálákà bëê náà: ó þ ÿiÿë gëgë bí òÿìÿë kékeré nílé-iÿë þlá kan, bëê ni kò sì tôrô jç, ÿùgbön ó kàn jë pé kò lówó tó Ayõkúnlé Atáyéwá, oníÿòwò kan tí baba Fôláÿadé fë kí ômô rê fë. Ìyá Fôláÿadé náà sì rèé, ibi tí ôkô rê bá tê sí ni òun náà þ tê sí. ßé ojúbõrõ kö ni a sì fi þ gbômô löwö èkùrö: àwôn òbí Fôláÿadé fi toògùn-toògùn fa ômô wôn fún Ayõkúnlé Atáyéwá ÿaya. Babárìndé banújë nídìí õrõ yìí, êdùn-ôkàn sì ni Fôláÿadé gbé wôlé ôkô.
Ôjö þ gorí ôjö, ôdún þ gorí ôdún, bëê ni ìgbà sì þ rékôjá lo. Fôláÿadé bí akô, ó bi abo nílé ôkô, ÿúgbön nýkan ò lô déédé fún ôkô rê mö lënu òwò rè. Àwôn oníbodè ti gbësê lé ôjà rê tó jë çgbêlëgbê náírà. Ó yáwó nílé-ìfowópamö, ÿùgbön kò rí i san padà. Àwôn báýkì bá gba ilé, ôkõ àti àwôn dúkìá rê mìíràn. Àtijç-àtimu wá di ìÿòro fún òun àti ìyàwó rê àti àwon ômô wôn pêlú.
Níhà kejì, Babárìndé náà ti gbéyàwó, ó sì tí bímô. Lënu iÿë rê wàyìí, ó ti di õgá, orí sì ti sún un sölá. Àwôn òbí Fôláÿadé wá þ wò sùnùn, wön rí i bí ìgbé-ayé Ayõkúnlé Atáyéwá ÿe þ lô, wön sì tún wo ti Fôláÿadé ômô wôn, bákan náà ni wön sì þ gbókèèrè wo ti Babárìndé bó ÿe þ dùn sí i fún un. Wön wá fika àbámò bônu: iwájú ò ÿeé lô, èyìn ò sì ÿeé padà sí fún wôn. Babárìndé, eni tí wôn rò pé kò lè pàgö ló wá dçni tí þ kölé aláruru. Ó wá hàn kedere sí wôn pé çni tí yóò dôlölà löla, orí ló mõ ön.
Kí ni ó fà á ti baba Föláÿadé fi kórìíra Babárìndé?
Antwortdetails
Òtòÿì ni Babárìndé.
Frage 49 Bericht
ÌßÊßE
Àbùdá ômôlúàbí ni kí ó
Frage 50 Bericht
ÈDÈ
Orí àpólà-ìÿe ni
Antwortdetails
Láti orí àpólà-iÿe ni õrõ-ìÿe lílo yóò ti bêrê.
Möchten Sie mit dieser Aktion fortfahren?