Nkojọpọ....
Tẹ mọ́ & Dì mú láti fà yíká. |
|||
Tẹ ibi lati pa |
Ibeere 1 Ìròyìn
ÈDÈ
ße ìtumõ ‘Uneasy lies the head that wears a crown’.
Ibeere 2 Ìròyìn
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Orí loníÿe, êdá làyànmö.
Àkúnlêyàn òun ni àdáyébá.
A délé ayé tán ojú þ kán gbogbo wa;
Orí níí ÿatökùn fúnni.
Ìgbà ti ara ènìyàn kò yá,
Òògùn ló lôjö kan ìpönjú,
Orí ló lôjö gbogbo.
Orí çni làwúre çni;
Orí ló yç kénìyàn ó sìn.
Báa bá wálé ayé táa lówó löwö,
Àyànmö ni.
Bí a sì wà lókèèrè, táyé þ yö wa wò níkõrõ,
ßebí orí ló sohun gbogbo.
Ohun ti Táyé þ ÿe tó fi lówó löwö,
Òun ni Këhìndé ÿe tó dolòsì.
Ç má fõrõ àyànmö wéra.
Nítori ohun ti a yàn, õtõõtõ ni,
Báyé bá yçni, ÿebí orí inú çni ni.
Báa bá dènìyàn þlá, ohun táa dì mö kádàrá ni.
Ohun ti a rù lórí, látòde õrun wá ni.
Kò séèyàn ti í paÿô àgùntàn-án dà.
Táyé bá ÿelá tílá fi kó,
Téniyàn ÿekàn tíkàn bá wêwù êjê
Táyé náà bá tún taÿô ìjímèrè bepo
Ká rántí pé ohun táa mú wáyé látòde õrun ni
Kò sëni pa Lágbájá,
Kò sëni pa Làkáÿègbè;
Ó ti wà nínú àkôölê rê ni.
Orí jà ó joògùn
Orí là bá máa bô löjö gbogbo
Orí ni ààbò çni,
Kò sórìÿà ti þ gbeni lëyìn orí çni.
Bénìyàn bá ní wàhálà, orí ni yóò ké sí.
Máà bënìkan sô,
Nítorí ènìyàn kò fêni förõ, à forí çni.
Nínú ìlà 14-15, ohun ti akéwì sô nípa Táyé àti Këhìndé ni pé
Awọn alaye Idahun
Yorùbá a máa wí pé “Ibi tí Táyé tí yan orí, Këhìndé kò yan tirê níbê”.
Ibeere 3 Ìròyìn
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Àbíkú S’olóògùn D’èké ni ìbéèrè dá lé.
Ta ni ó sô pé, ‘kì í ÿe çni méje ni ç ó pa, a ti di méjô’?
Ibeere 4 Ìròyìn
ÌßÊßE
Òrìÿà ti àwôn Yorùbá gbàgbö pé ó jé àpççrç àwôn baba-þlá tó ti kú ni
Awọn alaye Idahun
Ìdí nìyçn tí wön fi þ ki awôn eégún ní ‘ará õrun kìninkin’.
Ibeere 6 Ìròyìn
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Orí loníÿe, êdá làyànmö.
Àkúnlêyàn òun ni àdáyébá.
A délé ayé tán ojú þ kán gbogbo wa;
Orí níí ÿatökùn fúnni.
Ìgbà ti ara ènìyàn kò yá,
Òògùn ló lôjö kan ìpönjú,
Orí ló lôjö gbogbo.
Orí çni làwúre çni;
Orí ló yç kénìyàn ó sìn.
Báa bá wálé ayé táa lówó löwö,
Àyànmö ni.
Bí a sì wà lókèèrè, táyé þ yö wa wò níkõrõ,
ßebí orí ló sohun gbogbo.
Ohun ti Táyé þ ÿe tó fi lówó löwö,
Òun ni Këhìndé ÿe tó dolòsì.
Ç má fõrõ àyànmö wéra.
Nítori ohun ti a yàn, õtõõtõ ni,
Báyé bá yçni, ÿebí orí inú çni ni.
Báa bá dènìyàn þlá, ohun táa dì mö kádàrá ni.
Ohun ti a rù lórí, látòde õrun wá ni.
Kò séèyàn ti í paÿô àgùntàn-án dà.
Táyé bá ÿelá tílá fi kó,
Téniyàn ÿekàn tíkàn bá wêwù êjê
Táyé náà bá tún taÿô ìjímèrè bepo
Ká rántí pé ohun táa mú wáyé látòde õrun ni
Kò sëni pa Lágbájá,
Kò sëni pa Làkáÿègbè;
Ó ti wà nínú àkôölê rê ni.
Orí jà ó joògùn
Orí là bá máa bô löjö gbogbo
Orí ni ààbò çni,
Kò sórìÿà ti þ gbeni lëyìn orí çni.
Bénìyàn bá ní wàhálà, orí ni yóò ké sí.
Máà bënìkan sô,
Nítorí ènìyàn kò fêni förõ, à forí çni.
Kókó inú ewì yìí ni pé
Awọn alaye Idahun
Ohun tí a bá ti yàn löwö orí láti ìsálú õrun kò ÿe é yí padà
Ibeere 7 Ìròyìn
ÈDÈ
Àtúnkô fún Adé na Olú nípa lílo õrõ-aröpò-orúkô dípò Olú ni
Ibeere 8 Ìròyìn
ÌßÊßE
Àwôn Yorùbá máa þ lo ewé efinrin fún
Awọn alaye Idahun
Eyí ní í ÿe pêlú ìgbàgbö Yorùbá nípa òògùn ìbílê.
Ibeere 9 Ìròyìn
LÍTÍRÉßÕ
Kí ni Õkánlàwön pè ní obì àwôn káþsëlõ?
Awọn alaye Idahun
Àdàpè owó ni obì, tàbí ÿôwökúdúrú.
Ibeere 10 Ìròyìn
Awọn alaye Idahun
Wôn þ ÿe eléyìí láti tàbùkù ìyàwo tí ôkô rê kò bá nílé àti àwôn òbí rê ni.
Ibeere 11 Ìròyìn
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Ôba Fadérera ní oko kòkó àti oko obì, ó ní oko iÿu àti oko òwú, ilá inú oko rè ni gbogbo ìlú gbójú lé, iÿu àkùrõ rê níí kökö yôjú sí ôjà. Oko ôba gbòòrò púpõ.Sé ìgbà púpõ ni õpõlôpõ ènìyàn þ lô láti ÿiÿç õfë fún ôba. Ôba tún fi ôgbôn ÿe é tó bëê tí irè oko rê kò wön tó ti çlòmíràn.
Ôba Fadérera bí ômôkùnrin kan tí ó fëràn púpõ. Ômô ôba yìí kì í ÿe iÿë kankan, àfi ki ó máa ÿiré nínu ôgbà baba rê. Àwôn ìránÿë põ láti fún un ní gbogbo ohun tí ó bá þ fë. Aÿô tuntun ni ômô ôba þ wõ ní ojoojúmö. Ôba kë ômô náà bí çyin ojú, ó kë ç pêlú ohun ìní àti ìránÿë.
Ohun kan wá jë êdùn ôkàn àwôn ará ìlú Êyìn-Õla. Ohun náà ni pé, ìkòokò a máa dédé wô ìlú láti gbé ewúrë tàbí àgùntàn wôn lô. Ní ìgbà púpõ ni àwôn ará ìlú ti lô ké bá ôba kí ó bá àwôn yanjú õràn tí ó dé bá wôn. Nígbà tí ó ÿe wàyí o, àwôn ìkòokò pàápàá wá tún ara mú, wön bêrê sí í gbé àwôn ômô ará ìlú Êyìn-õla. Àwôn ìlú tún ké lô sí õdõ õba, ÿùgbön ôba kò ka õrõ náà sí rárá.
Ní ôjö kan nígbà tí ômô ôba Fadérera àti àwôn çmêwà bàbá rê þ ÿiré lórí pápá tí ó wà lëbàá ààfin, ìkòokò þlá kan yô sí wôn, ó sì gbé ômô ôba lô ráúráú. Nígbà tí ôba gbö ohun tí ó ÿçlê, ó kígbe ní ohùn rara.
Õrõ náà wá ya gbogbo ìlú lënu nítorí pé ôba pàÿç lësêkçsê pé kí gbogbo àwôn ôdç atamátàsé ìlú jáde, kí wön sì pa gbogbo ìkòokò tí ó wà agbègbè náà. Sùgbön ìkòokò tí pa ômô ôba Fadérera jç. Êpa kò bóró mö.
Asõtàn fi Ôba Fadérera hàn bíi
Awọn alaye Idahun
Ôba Fadérera þ fi àwôn ènìyàn ìlú gún lágídí nígbá tí wön bá lö sô fún un pè ìkookò pa çran wôn.
Ibeere 12 Ìròyìn
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Ojú Òÿùpá, apá kìíní ni ìbéèrè dá lé.
Nínú ìtàn Ìjà Ìlêkê, kí ni Kékeré awo ní kí ôba fi bô òrìÿà odù?
Ibeere 13 Ìròyìn
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Ìwúre Níbi Àÿeyç ni ìbéèrè dá lé.
Nínú Ìwúre Níbi Ìköÿëyege, tá ló köÿë yege?
Awọn alaye Idahun
Ìwé Ìwúre Níbi Àÿeyç is a Yoruba Christian hymnal containing various hymns for use during worship. Within the hymn called Ìköÿëyege, there is a call-and-response section where the leader says a phrase and the congregation responds with another phrase. The correct response to the phrase "Tá ló köÿë yege?" is "Àdùkë", which means "The righteous one."
Ibeere 14 Ìròyìn
ÌßÊßE
Òdiwõn ojúgbà láàrin ìlú ni
Awọn alaye Idahun
Çgbë çnì tàbí akçgbë çni ni çni tí a jô jç ômô ôdún kan náà tàbí tí a fi osù díê ju ara wa lô.
Ibeere 15 Ìròyìn
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Ôba Fadérera ní oko kòkó àti oko obì, ó ní oko iÿu àti oko òwú, ilá inú oko rè ni gbogbo ìlú gbójú lé, iÿu àkùrõ rê níí kökö yôjú sí ôjà. Oko ôba gbòòrò púpõ.Sé ìgbà púpõ ni õpõlôpõ ènìyàn þ lô láti ÿiÿç õfë fún ôba. Ôba tún fi ôgbôn ÿe é tó bëê tí irè oko rê kò wön tó ti çlòmíràn.
Ôba Fadérera bí ômôkùnrin kan tí ó fëràn púpõ. Ômô ôba yìí kì í ÿe iÿë kankan, àfi ki ó máa ÿiré nínu ôgbà baba rê. Àwôn ìránÿë põ láti fún un ní gbogbo ohun tí ó bá þ fë. Aÿô tuntun ni ômô ôba þ wõ ní ojoojúmö. Ôba kë ômô náà bí çyin ojú, ó kë ç pêlú ohun ìní àti ìránÿë.
Ohun kan wá jë êdùn ôkàn àwôn ará ìlú Êyìn-Õla. Ohun náà ni pé, ìkòokò a máa dédé wô ìlú láti gbé ewúrë tàbí àgùntàn wôn lô. Ní ìgbà púpõ ni àwôn ará ìlú ti lô ké bá ôba kí ó bá àwôn yanjú õràn tí ó dé bá wôn. Nígbà tí ó ÿe wàyí o, àwôn ìkòokò pàápàá wá tún ara mú, wön bêrê sí í gbé àwôn ômô ará ìlú Êyìn-õla. Àwôn ìlú tún ké lô sí õdõ õba, ÿùgbön ôba kò ka õrõ náà sí rárá.
Ní ôjö kan nígbà tí ômô ôba Fadérera àti àwôn çmêwà bàbá rê þ ÿiré lórí pápá tí ó wà lëbàá ààfin, ìkòokò þlá kan yô sí wôn, ó sì gbé ômô ôba lô ráúráú. Nígbà tí ôba gbö ohun tí ó ÿçlê, ó kígbe ní ohùn rara.
Õrõ náà wá ya gbogbo ìlú lënu nítorí pé ôba pàÿç lësêkçsê pé kí gbogbo àwôn ôdç atamátàsé ìlú jáde, kí wön sì pa gbogbo ìkòokò tí ó wà agbègbè náà. Sùgbön ìkòokò tí pa ômô ôba Fadérera jç. Êpa kò bóró mö.
Ohun ti ó mú irè oko ôba tà ju ti ará ìlú lô ni pé
Awọn alaye Idahun
The passage is written in Yoruba, a language spoken in Nigeria, and the question asks about a specific event mentioned in the text. Based on the context, the answer is that "irè oko ôba kò wön" (the harvest of the king's farm did not belong to them). This is because the passage describes how the people of the town were ordered by the king to bring all their crops to him and how a certain man named Fadérera had a bountiful harvest on his farm. However, when the king asked for his share, Fadérera did not give him any because the harvest did not belong to him, but to the gods. As a result, the king became angry and punished Fadérera.
Ibeere 16 Ìròyìn
ÌßÊßE
Õkan lára ohun-èlò ti Yorùbá fi máa þ ÿe õÿö sí ara ômô tuntun ni
Awọn alaye Idahun
Yorùbá a ní “kì í tán nínú igbá osùn ká má rí fi pa ômô lára”.
Ibeere 17 Ìròyìn
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Àjà ló lçrù ni ìbéèrè dá lé.
Níbo ni àwôn ôlöpàá ti rí oko igbó?
Awọn alaye Idahun
ße ni wön dôdç àwôn òdaràn dé ibê
Ibeere 18 Ìròyìn
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Àjà ló lçrù ni ìbéèrè dá lé.
Iÿë wo ni Lápàdé bêrê sí ´ÿe ní kété ti ó fi iÿë ôlöpàá sílè?
Ibeere 20 Ìròyìn
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Orí loníÿe, êdá làyànmö.
Àkúnlêyàn òun ni àdáyébá.
A délé ayé tán ojú þ kán gbogbo wa;
Orí níí ÿatökùn fúnni.
Ìgbà ti ara ènìyàn kò yá,
Òògùn ló lôjö kan ìpönjú,
Orí ló lôjö gbogbo.
Orí çni làwúre çni;
Orí ló yç kénìyàn ó sìn.
Báa bá wálé ayé táa lówó löwö,
Àyànmö ni.
Bí a sì wà lókèèrè, táyé þ yö wa wò níkõrõ,
ßebí orí ló sohun gbogbo.
Ohun ti Táyé þ ÿe tó fi lówó löwö,
Òun ni Këhìndé ÿe tó dolòsì.
Ç má fõrõ àyànmö wéra.
Nítori ohun ti a yàn, õtõõtõ ni,
Báyé bá yçni, ÿebí orí inú çni ni.
Báa bá dènìyàn þlá, ohun táa dì mö kádàrá ni.
Ohun ti a rù lórí, látòde õrun wá ni.
Kò séèyàn ti í paÿô àgùntàn-án dà.
Táyé bá ÿelá tílá fi kó,
Téniyàn ÿekàn tíkàn bá wêwù êjê
Táyé náà bá tún taÿô ìjímèrè bepo
Ká rántí pé ohun táa mú wáyé látòde õrun ni
Kò sëni pa Lágbájá,
Kò sëni pa Làkáÿègbè;
Ó ti wà nínú àkôölê rê ni.
Orí jà ó joògùn
Orí là bá máa bô löjö gbogbo
Orí ni ààbò çni,
Kò sórìÿà ti þ gbeni lëyìn orí çni.
Bénìyàn bá ní wàhálà, orí ni yóò ké sí.
Máà bënìkan sô,
Nítorí ènìyàn kò fêni förõ, à forí çni.
A délé ayé tán ojú þ kán gbogbo wa túmõ sí péAwọn alaye Idahun
Èyí ni pé àwa êda kì í yan sùúrù láàyò nínú ohun tí a þ ÿe
Ibeere 21 Ìròyìn
ÈDÈ
Fi àmì-ohùn tó tõnà sórí Olubôbôtiribô láti fún un ní ìtumõ tó péye.
Awọn alaye Idahun
Ibeere 22 Ìròyìn
ÈDÈ
‘Owó tí mo yá tán’
Irú awë-gbólóhùn wo ni tí mo yá?
Awọn alaye Idahun
The proverb ‘Owó tì mo yá tán’ is in the Yoruba language, one of the major languages spoken in Nigeria. It translates to "The hand that I used to eat is the same hand that I used to dig the grave". The proverb means that the same resources or tools that one uses to achieve success or accomplishment can also be used to bring about one's downfall or failure. The answer to the question "Irú awë-gbólóhùn wo ni tì mo yá?" is Aÿàpèjúwe. This is because the phrase "tì mo yá tán" is a popular saying in Yoruba culture, and it is commonly associated with the Aÿàpèjúwe drum.
Ibeere 23 Ìròyìn
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Orí loníÿe, êdá làyànmö.
Àkúnlêyàn òun ni àdáyébá.
A délé ayé tán ojú þ kán gbogbo wa;
Orí níí ÿatökùn fúnni.
Ìgbà ti ara ènìyàn kò yá,
Òògùn ló lôjö kan ìpönjú,
Orí ló lôjö gbogbo.
Orí çni làwúre çni;
Orí ló yç kénìyàn ó sìn.
Báa bá wálé ayé táa lówó löwö,
Àyànmö ni.
Bí a sì wà lókèèrè, táyé þ yö wa wò níkõrõ,
ßebí orí ló sohun gbogbo.
Ohun ti Táyé þ ÿe tó fi lówó löwö,
Òun ni Këhìndé ÿe tó dolòsì.
Ç má fõrõ àyànmö wéra.
Nítori ohun ti a yàn, õtõõtõ ni,
Báyé bá yçni, ÿebí orí inú çni ni.
Báa bá dènìyàn þlá, ohun táa dì mö kádàrá ni.
Ohun ti a rù lórí, látòde õrun wá ni.
Kò séèyàn ti í paÿô àgùntàn-án dà.
Táyé bá ÿelá tílá fi kó,
Téniyàn ÿekàn tíkàn bá wêwù êjê
Táyé náà bá tún taÿô ìjímèrè bepo
Ká rántí pé ohun táa mú wáyé látòde õrun ni
Kò sëni pa Lágbájá,
Kò sëni pa Làkáÿègbè;
Ó ti wà nínú àkôölê rê ni.
Orí jà ó joògùn
Orí là bá máa bô löjö gbogbo
Orí ni ààbò çni,
Kò sórìÿà ti þ gbeni lëyìn orí çni.
Bénìyàn bá ní wàhálà, orí ni yóò ké sí.
Máà bënìkan sô,
Nítorí ènìyàn kò fêni förõ, à forí çni.
Ìtumõ kádàrá nínú ewì yìí ni
Awọn alaye Idahun
The theme or moral lesson of this poem is about the importance of destiny, or "kádàrá" in Yoruba language. The poem emphasizes that destiny is determined by one's head or inner being, and that no one can change it. It also suggests that when one is facing difficulties in life, they should trust in their destiny and not lose hope, as it is their ultimate guide. Therefore, the answer is "ìpín", which means "destiny" in Yoruba language.
Ibeere 24 Ìròyìn
ÈDÈ
‘Ìwô ni’
Nínú gbólóhùn yìí, ni jë õrõ
Awọn alaye Idahun
“ni” nìkan ni ó ÿìÿë õrõ-ìÿe nínú gbólóhùn yìí.
Ibeere 25 Ìròyìn
ÌßÊßE
Ká ní õyàyà, ká kóni möra, ká sì ÿe ohun tó tö ní ìwà
Awọn alaye Idahun
Ìwõnyí jë díê nínú àwôn ìwà rere t’o gbödõ jç ômôlúwàbí lógún.
Ibeere 26 Ìròyìn
ÈDÈ
Ète môfölõjì tí a lò láti ÿêdá ômôkömô ni
Ibeere 27 Ìròyìn
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Àjà ló lçrù ni ìbéèrè dá lé.
Ta ni awakõ mötò WOT 0024 tí ó ÿe jàýbá?
Awọn alaye Idahun
Tá íwò ló wa ôkõ ní ìwàkuwà.
Ibeere 28 Ìròyìn
ÈDÈ
Gbólóhùn tó fi àsìkò afànámónìí hàn ni
Awọn alaye Idahun
Gbólóhùn yìí fi hàn pé çni náà ti lô ÿùgbön kò fi àkokò tó lô hàn.
Ibeere 29 Ìròyìn
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Ààrò Mëta ni ìbéèrè dá lé.
Nínú Èkùrö Lalábàákú Êwà, akéwì sô pè òun ní ìfë àtôkànwà sí
Awọn alaye Idahun
Nítorí pé ó pë tó ti þ fi ìfë kéwì, kì í ÿe nítorí àtijç nikan.
Ibeere 31 Ìròyìn
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Ôba Fadérera ní oko kòkó àti oko obì, ó ní oko iÿu àti oko òwú, ilá inú oko rè ni gbogbo ìlú gbójú lé, iÿu àkùrõ rê níí kökö yôjú sí ôjà. Oko ôba gbòòrò púpõ.Sé ìgbà púpõ ni õpõlôpõ ènìyàn þ lô láti ÿiÿç õfë fún ôba. Ôba tún fi ôgbôn ÿe é tó bëê tí irè oko rê kò wön tó ti çlòmíràn.
Ôba Fadérera bí ômôkùnrin kan tí ó fëràn púpõ. Ômô ôba yìí kì í ÿe iÿë kankan, àfi ki ó máa ÿiré nínu ôgbà baba rê. Àwôn ìránÿë põ láti fún un ní gbogbo ohun tí ó bá þ fë. Aÿô tuntun ni ômô ôba þ wõ ní ojoojúmö. Ôba kë ômô náà bí çyin ojú, ó kë ç pêlú ohun ìní àti ìránÿë.
Ohun kan wá jë êdùn ôkàn àwôn ará ìlú Êyìn-Õla. Ohun náà ni pé, ìkòokò a máa dédé wô ìlú láti gbé ewúrë tàbí àgùntàn wôn lô. Ní ìgbà púpõ ni àwôn ará ìlú ti lô ké bá ôba kí ó bá àwôn yanjú õràn tí ó dé bá wôn. Nígbà tí ó ÿe wàyí o, àwôn ìkòokò pàápàá wá tún ara mú, wön bêrê sí í gbé àwôn ômô ará ìlú Êyìn-õla. Àwôn ìlú tún ké lô sí õdõ õba, ÿùgbön ôba kò ka õrõ náà sí rárá.
Ní ôjö kan nígbà tí ômô ôba Fadérera àti àwôn çmêwà bàbá rê þ ÿiré lórí pápá tí ó wà lëbàá ààfin, ìkòokò þlá kan yô sí wôn, ó sì gbé ômô ôba lô ráúráú. Nígbà tí ôba gbö ohun tí ó ÿçlê, ó kígbe ní ohùn rara.
Õrõ náà wá ya gbogbo ìlú lënu nítorí pé ôba pàÿç lësêkçsê pé kí gbogbo àwôn ôdç atamátàsé ìlú jáde, kí wön sì pa gbogbo ìkòokò tí ó wà agbègbè náà. Sùgbön ìkòokò tí pa ômô ôba Fadérera jç. Êpa kò bóró mö.
Ìtumõ ráúráú nínú àyôkà yìí ni
Ibeere 32 Ìròyìn
ÌßÊßE
‘Tìpêtipç-n-tìrán:Ikun imú arúgbó kì í já bõrõbõrõTìpêtipç-n-tìrán’.
Ibi eré ìdárayá wo ni a ti sábà máa þ gbó ìpèdè òkè yìí?
Awọn alaye Idahun
Çkç jë õkan nínú eré ìdárayá nílê Yorúbá. Wön þ pe ìpèdè yìí nígbàtí wón bá þ lö tínínrín.
Ibeere 33 Ìròyìn
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Ààrò Mëta ni ìbéèrè dá lé.
Nínú Ìtëlörùn çni tí ó ní ìtëlörùn náà ni ó
Awọn alaye Idahun
Èyí ni çni tó gbà pé bí a se wáyé kì í yê.
Ibeere 34 Ìròyìn
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Ìwúre Níbi Àÿeyç ni ìbéèrè dá lé.
Nínú Ìwúre Níbi Àsè Ìgbéyàwó, awúre sô pé àbímôlémô ni ti eku çdá, kí ló pe ti àtôlêdölê?
Awọn alaye Idahun
Àdán kì í gùn bëê ní won kì í yé bíí ti àwôn çyç yòókù; a máa n bá ômô nínú ômô wôn ni.
Ibeere 35 Ìròyìn
ÌßÊßE
Çgbë awo tó þ kópa pàtàkì nínú ètò ìÿèlú láyé àtijö ni
Awọn alaye Idahun
Àwôn ômô çgbë ògbóni ni wön þ bójútó ètò ìÿèlú láyé àtijö.
Ibeere 36 Ìròyìn
ÈDÈ
‘Një o gbö kí o panumö’, jë gbólóhùn
Awọn alaye Idahun
Panumö ni èdè àÿç tó wà n’inú gbólóhùn náà.
Ibeere 37 Ìròyìn
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Ààrò Mëta ni ìbéèrè dá lé.
‘Ilé ayé kò tó nýkan
Àtubõtán làgbà nínú ohun tó wà lókè eèpê ...
ßùgbön ôjö àtisùn lçbô’
Nínú Àtubõtán, àtubõtán túmö sí
Awọn alaye Idahun
Èyí ni ìgbà tí a bá ti dàgbà, tí ôjö ayé çni kò pë mö.
Ibeere 38 Ìròyìn
ÈDÈ
Õrõ wo ni kò ní apààlà sílébù nínú Olú á ra bàtà?
Awọn alaye Idahun
“Á” nìkan ni kò ÿe é gé sí sílébú nínú gbogbo õrõ inú gbólóhùn náà.
Ibeere 39 Ìròyìn
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Àbíkú S’olóògùn D’èké ni ìbéèrè dá lé.
Ìdí tí Sùnmönù àti àwôn õrë rê fi gbìmo láti bç õwê sí ßêgbêjí ni pé
Awọn alaye Idahun
Èrò ti wôn ni pé ilé-çjö yóò ju ÿêgbêjí olóògùn sëwõn ÿùgbön ibi tí wön fójú sí, õnà kò gbabê.
Ibeere 40 Ìròyìn
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Ôba Fadérera ní oko kòkó àti oko obì, ó ní oko iÿu àti oko òwú, ilá inú oko rè ni gbogbo ìlú gbójú lé, iÿu àkùrõ rê níí kökö yôjú sí ôjà. Oko ôba gbòòrò púpõ.Sé ìgbà púpõ ni õpõlôpõ ènìyàn þ lô láti ÿiÿç õfë fún ôba. Ôba tún fi ôgbôn ÿe é tó bëê tí irè oko rê kò wön tó ti çlòmíràn.
Ôba Fadérera bí ômôkùnrin kan tí ó fëràn púpõ. Ômô ôba yìí kì í ÿe iÿë kankan, àfi ki ó máa ÿiré nínu ôgbà baba rê. Àwôn ìránÿë põ láti fún un ní gbogbo ohun tí ó bá þ fë. Aÿô tuntun ni ômô ôba þ wõ ní ojoojúmö. Ôba kë ômô náà bí çyin ojú, ó kë ç pêlú ohun ìní àti ìránÿë.
Ohun kan wá jë êdùn ôkàn àwôn ará ìlú Êyìn-Õla. Ohun náà ni pé, ìkòokò a máa dédé wô ìlú láti gbé ewúrë tàbí àgùntàn wôn lô. Ní ìgbà púpõ ni àwôn ará ìlú ti lô ké bá ôba kí ó bá àwôn yanjú õràn tí ó dé bá wôn. Nígbà tí ó ÿe wàyí o, àwôn ìkòokò pàápàá wá tún ara mú, wön bêrê sí í gbé àwôn ômô ará ìlú Êyìn-õla. Àwôn ìlú tún ké lô sí õdõ õba, ÿùgbön ôba kò ka õrõ náà sí rárá.
Ní ôjö kan nígbà tí ômô ôba Fadérera àti àwôn çmêwà bàbá rê þ ÿiré lórí pápá tí ó wà lëbàá ààfin, ìkòokò þlá kan yô sí wôn, ó sì gbé ômô ôba lô ráúráú. Nígbà tí ôba gbö ohun tí ó ÿçlê, ó kígbe ní ohùn rara.
Õrõ náà wá ya gbogbo ìlú lënu nítorí pé ôba pàÿç lësêkçsê pé kí gbogbo àwôn ôdç atamátàsé ìlú jáde, kí wön sì pa gbogbo ìkòokò tí ó wà agbègbè náà. Sùgbön ìkòokò tí pa ômô ôba Fadérera jç. Êpa kò bóró mö.
Kí ni ó fún Ôba Fadérera lólìkí?
Ibeere 41 Ìròyìn
ÈDÈ
Ìrókíròó tí a bá pè nígbà ti ìdíwö wà fún èémí ni
Awọn alaye Idahun
Àpççrç ni b, d àti k.
Ibeere 42 Ìròyìn
ÈDÈ
Õrõ-aröpò-orúkô çnì kìíní õpõ ní ipò àbõ ni
Awọn alaye Idahun
Bí àpççrç, Olú ti rí wa
dípò Olú ti rí Adé, Olú àti èmi.
Ibeere 43 Ìròyìn
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Orí loníÿe, êdá làyànmö.
Àkúnlêyàn òun ni àdáyébá.
A délé ayé tán ojú þ kán gbogbo wa;
Orí níí ÿatökùn fúnni.
Ìgbà ti ara ènìyàn kò yá,
Òògùn ló lôjö kan ìpönjú,
Orí ló lôjö gbogbo.
Orí çni làwúre çni;
Orí ló yç kénìyàn ó sìn.
Báa bá wálé ayé táa lówó löwö,
Àyànmö ni.
Bí a sì wà lókèèrè, táyé þ yö wa wò níkõrõ,
ßebí orí ló sohun gbogbo.
Ohun ti Táyé þ ÿe tó fi lówó löwö,
Òun ni Këhìndé ÿe tó dolòsì.
Ç má fõrõ àyànmö wéra.
Nítori ohun ti a yàn, õtõõtõ ni,
Báyé bá yçni, ÿebí orí inú çni ni.
Báa bá dènìyàn þlá, ohun táa dì mö kádàrá ni.
Ohun ti a rù lórí, látòde õrun wá ni.
Kò séèyàn ti í paÿô àgùntàn-án dà.
Táyé bá ÿelá tílá fi kó,
Téniyàn ÿekàn tíkàn bá wêwù êjê
Táyé náà bá tún taÿô ìjímèrè bepo
Ká rántí pé ohun táa mú wáyé látòde õrun ni
Kò sëni pa Lágbájá,
Kò sëni pa Làkáÿègbè;
Ó ti wà nínú àkôölê rê ni.
Orí jà ó joògùn
Orí là bá máa bô löjö gbogbo
Orí ni ààbò çni,
Kò sórìÿà ti þ gbeni lëyìn orí çni.
Bénìyàn bá ní wàhálà, orí ni yóò ké sí.
Máà bënìkan sô,
Nítorí ènìyàn kò fêni förõ, à forí çni.
Ìdí ti akéwì fi ní ká bórí sô ká máà bënìkan sô ni pé
Awọn alaye Idahun
Yorùbá þ pa á lówe pé “Ènìyàn kò fê ká rçrù ká sõ, orí çni ló þ yôní”
Ibeere 44 Ìròyìn
ÈDÈ
ße ìtumõ ‘I am at my wits’ end on this issue’.
Ibeere 45 Ìròyìn
ÈDÈ
Éwo ló bá ìlànà àkôtö òde-òní mu?
Awọn alaye Idahun
Gbólóhùn yíì ló bá ìlànà àkôtö òde-òní mu dáadáa.
Ibeere 46 Ìròyìn
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
Ôba Fadérera ní oko kòkó àti oko obì, ó ní oko iÿu àti oko òwú, ilá inú oko rè ni gbogbo ìlú gbójú lé, iÿu àkùrõ rê níí kökö yôjú sí ôjà. Oko ôba gbòòrò púpõ.Sé ìgbà púpõ ni õpõlôpõ ènìyàn þ lô láti ÿiÿç õfë fún ôba. Ôba tún fi ôgbôn ÿe é tó bëê tí irè oko rê kò wön tó ti çlòmíràn.
Ôba Fadérera bí ômôkùnrin kan tí ó fëràn púpõ. Ômô ôba yìí kì í ÿe iÿë kankan, àfi ki ó máa ÿiré nínu ôgbà baba rê. Àwôn ìránÿë põ láti fún un ní gbogbo ohun tí ó bá þ fë. Aÿô tuntun ni ômô ôba þ wõ ní ojoojúmö. Ôba kë ômô náà bí çyin ojú, ó kë ç pêlú ohun ìní àti ìránÿë.
Ohun kan wá jë êdùn ôkàn àwôn ará ìlú Êyìn-Õla. Ohun náà ni pé, ìkòokò a máa dédé wô ìlú láti gbé ewúrë tàbí àgùntàn wôn lô. Ní ìgbà púpõ ni àwôn ará ìlú ti lô ké bá ôba kí ó bá àwôn yanjú õràn tí ó dé bá wôn. Nígbà tí ó ÿe wàyí o, àwôn ìkòokò pàápàá wá tún ara mú, wön bêrê sí í gbé àwôn ômô ará ìlú Êyìn-õla. Àwôn ìlú tún ké lô sí õdõ õba, ÿùgbön ôba kò ka õrõ náà sí rárá.
Ní ôjö kan nígbà tí ômô ôba Fadérera àti àwôn çmêwà bàbá rê þ ÿiré lórí pápá tí ó wà lëbàá ààfin, ìkòokò þlá kan yô sí wôn, ó sì gbé ômô ôba lô ráúráú. Nígbà tí ôba gbö ohun tí ó ÿçlê, ó kígbe ní ohùn rara.
Õrõ náà wá ya gbogbo ìlú lënu nítorí pé ôba pàÿç lësêkçsê pé kí gbogbo àwôn ôdç atamátàsé ìlú jáde, kí wön sì pa gbogbo ìkòokò tí ó wà agbègbè náà. Sùgbön ìkòokò tí pa ômô ôba Fadérera jç. Êpa kò bóró mö.
Êdùn ôkàn àwôn ará ìlú Êyìn-Õla ni
Awọn alaye Idahun
The passage is written in the Yoruba language, and it tells a story about a king named Oba Faderera and the people of his city, Eyin-Ola. The question asks for the meaning of "Edun Okan" among the people of Eyin-Ola. Based on the context of the story, "Edun Okan" refers to a festival or event that involves the sacrifice of a sheep or a goat to appease the gods or ancestors. The festival is significant to the people of Eyin-Ola, as it is a time of celebration and unity, where everyone comes together to participate in the sacrifice and feast. Therefore, "Ikooko ti o daamu ilu" (the festival of the city), is the correct answer.
Ibeere 47 Ìròyìn
Awọn alaye Idahun
Lëyìn ìfójúsóde, tí õdõkùnrin bá ti rí obìnrin tó wù ú láti fë, ojúÿe àwôn òbí ló kù làti ÿe ìwádìí nípa irú ilé tí ômôbìnrin náà ti wá.
Ibeere 48 Ìròyìn
ÈDÈ
Àpççrç õrõ àyálò níbi tí köþsónáýtì ti parí õrõ ni
Awọn alaye Idahun
Láti inú èdè Gêësì “thug” ni a ti yá õrõ yìí lò; ìlànà òfin õrõ Yorùbá ló jë ká fí fáwëlì i parí rê nígbà tí a pèé.
Ibeere 49 Ìròyìn
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Ìwúre Níbi Àÿeyç ni ìbéèrè dá lé.
‘Êyin bàbá wa tó wà níkàlê’
Nínú Ìwúre Níbi Àsè Ìÿílé, çsç òkè yìí töka sí àwôn
Awọn alaye Idahun
Èdè àpönlé ni baba jë fún àwôn ôba ti wôn wà ní ìkàlê.
Ibeere 50 Ìròyìn
LÍTÍRÉßÕ
Ìwé Ojú Òÿùpá, apá kìíní ni ìbéèrè dá lé.
Nínú ìtàn Oríkõ, kí ni Õrúnmìlà fi obì aláwë-mëta tí ó gbà löwö Jégéjégé ÿe?
Ṣe o fẹ tẹsiwaju pẹlu iṣe yii?