Loading....

JAMB UTME - Yoruba Language - 2002

Question 1 Report

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.

Ôba Fadérera ní oko kòkó àti oko obì, ó ní oko iÿu àti oko òwú, ilá inú oko rè ni gbogbo ìlú gbójú lé, iÿu àkùrõ rê níí kökö yôjú sí ôjà. Oko ôba gbòòrò púpõ.Sé ìgbà púpõ ni õpõlôpõ ènìyàn þ lô láti ÿiÿç õfë fún ôba. Ôba tún fi ôgbôn ÿe é tó bëê tí irè oko rê kò wön tó ti çlòmíràn.

Ôba Fadérera bí ômôkùnrin kan tí ó fëràn púpõ. Ômô ôba yìí kì í ÿe iÿë kankan, àfi ki ó máa ÿiré nínu ôgbà baba rê. Àwôn ìránÿë põ láti fún un ní gbogbo ohun tí ó bá þ fë. Aÿô tuntun ni ômô ôba þ wõ ní ojoojúmö. Ôba kë ômô náà bí çyin ojú, ó kë ç pêlú ohun ìní àti ìránÿë.

Ohun kan wá jë êdùn ôkàn àwôn ará ìlú Êyìn-Õla. Ohun náà ni pé, ìkòokò a máa dédé wô ìlú láti gbé ewúrë tàbí àgùntàn wôn lô. Ní ìgbà púpõ ni àwôn ará ìlú ti lô ké bá ôba kí ó bá àwôn yanjú õràn tí ó dé bá wôn. Nígbà tí ó ÿe wàyí o, àwôn ìkòokò pàápàá wá tún ara mú, wön bêrê sí í gbé àwôn ômô ará ìlú Êyìn-õla. Àwôn ìlú tún ké lô sí õdõ õba, ÿùgbön ôba kò ka õrõ náà sí rárá.

Ní ôjö kan nígbà tí ômô ôba Fadérera àti àwôn çmêwà bàbá rê þ ÿiré lórí pápá tí ó wà lëbàá ààfin, ìkòokò þlá kan yô sí wôn, ó sì gbé ômô ôba lô ráúráú. Nígbà tí ôba gbö ohun tí ó ÿçlê, ó kígbe ní ohùn rara.

Õrõ náà wá ya gbogbo ìlú lënu nítorí pé ôba pàÿç lësêkçsê pé kí gbogbo àwôn ôdç atamátàsé ìlú jáde, kí wön sì pa gbogbo ìkòokò tí ó wà agbègbè náà. Sùgbön ìkòokò tí pa ômô ôba Fadérera jç. Êpa kò bóró mö.

Ohun ti ó mú irè oko ôba tà ju ti ará ìlú lô ni pé