Loading....

JAMB UTME - Yoruba Language - 2007

Question 1 Report

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.

Ilé-ayé ò jë nýkan,

Àlá lásán ni,

Ôkàn tó þ sùn ti dòkú,

Nýkan ò rí bí a ti rò ó

Ilé-ayé gbçgë. 5

Sàréè ì ÿopin êdá.

Eérú fún eérú,

Eruku fún eruku,

Lôba-òkè sô fénìyàn,

Tó j’Ôlörun nípè. 10

Àmö hùwà bí çni pé,

Ojoojúmö lêdá þ súnmölé.

Máà gbëkêké ôlá

Máà nígbçkêlé nínú ôrõ.

Alágbára ayé, ç rôra ÿe. 15

Bí ó ti wù ká ki lökàn tó,

Kìkì ní í lù,

Báa bá gbölù ikú,

Àtorin arò ti þ kôjá lóde.

Ojú ogun layé. 20

Má bojú wêyìn,

Jà bí akin lójú ìjà.

Rántí ayé àkôni tó kôjá,

Wo àwòköÿe wôn fún ôjö õla tìrç.

Gbé ìgbé-ayé alààyè, 25

Jë kí òkú sunkún ara wôn.

Àwé, má ronú mö,

Jë ká máa ÿiÿé lô.

Máa jagun lô,

Má wêyìn, 30

Má ÿiyè méjì,

Bó pë, bó yá,

Ayõ þ bõ.

Kí ni akéwì sô pé yóò ÿe êdá tó gbö nípa ikú?